Psalms 106:44 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹsibẹ, ninu ìnira wọn, ó ṣàánú wọn, nígbà tí ó gbọ́ igbe wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ninu ipọnju o kiyesi wọn, nigbati o gbọ́ ẹkún wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n o kíyèsí wọn nítorí ìṣòro nígbà tí ó gbọ́ ẹkún wọn;