Psalms 106:46 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó jẹ́ kí àánú wọn ṣe gbogbo àwọn tí ó kó wọn ní ìgbèkùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mu wọn ri ãnu loju gbogbo awọn ti o kó wọn ni igbekun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lójú gbogbo àwọn tí o kó wọn ní ìgbèkùn ó mú wọn rí àánú.