Psalms 106:47 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbà wá, OLUWA, Ọlọrun wa, kí o sì kó wa kúrò láàrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, kí á lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ, kí á sì lè máa ṣògo ninu ìyìn rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa Ọlọrun wa, gbà wa, ki o si ṣa wa jọ kuro lãrin awọn keferi, lati ma fi ọpẹ fun orukọ mimọ́ rẹ, ati lati ma ṣogo ninu iyìn rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbà wá, OLÚWA Ọlọ́run wa, kí o sì ṣà wá jọ kúrò láàrin àwọn aláìkọlà láti máa fí ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ Rẹ láti máa ṣògo nínú ìyìn Rẹ.