Psalms 106:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Sibẹsibẹ, ó gbà wọ́n là, nítorí orúkọ rẹ̀; kí ó lè fi títóbi agbára rẹ̀ hàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn o gbà wọn là nitori orukọ rẹ̀, ki o le mu agbara rẹ̀ nla di mimọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n o gbà wọ́n là nítorí orúkọ Rẹ láti jẹ́ kí agbára ńlá Rẹ di mímọ̀