Psalms 106:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó bá òkun pupa wí, òkun pupa gbẹ, ó sì mú wọn la ibú já bí ẹni rìn ninu aṣálẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ba Okun pupa wi pẹlu, o si gbẹ: bẹ̃li o sìn wọn là ibu ja bi aginju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O bá òkun pupa wí, ó sì gbẹ; o sì mú wọn la ìbú já bí ihà