Psalms 107:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni wọ́n ké pe OLUWA ninu ìpọ́njú wọn, ó sì gbà wọ́n ninu ìṣẹ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si gbà wọn ninu iṣẹ́ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìgbà náà wọ́n ké pe OLÚWA nínú ìdàámú wọn, ó sì gbà wọ́n nínú ìṣòro wọn