Psalms 107:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kan ninu wọn di òmùgọ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, ojú sì pọ́n wọn nítorí àìdára wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aṣiwere nitori irekọja wọn, ati nitori ẹ̀ṣẹ wọn, oju npọ́n wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀pọ̀ di aṣiwèrè nítorí ìrékọjá wọn wọ́n sì pọ́n wọn lójú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn