Psalms 107:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni wọ́n ké pe OLUWA ninu ìpọ́njú wọn, ó sì yọ wọ́n ninu ìṣẹ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si gbà wọn ninu iṣẹ́ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà wọn kígbe sí OLÚWA nínú ìṣòro wọn, ó sì yọ wọ́n nínú ìdàámú wọn