Psalms 107:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọkọ̀ ojú omi fò sókè roro, wọ́n sì tún já wá sílẹ̀ dòò, sinu ibú, jìnnìjìnnì bò wọ́n ninu ewu tí wọ́n wà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn gòke lọ si ọrun, nwọn si tún sọkalẹ lọ si ibú; ọkàn wọn di omi nitori ipọnju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gòkè lọ sí ọ̀run wọn sì tún sọ̀kalẹ̀ lọ sí ibú: nítorí ìpọ́njú ọkan wọn di omi