Psalms 107:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni wọ́n ké pe OLUWA ninu ìpọ́njú wọn, ó sì yọ wọ́n ninu ìṣẹ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si yọ wọn kuro ninu iṣẹ́ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà wọ́n ń kígbe sókè sí OLÚWA nínú ìdàámú wọn, ó sì mú wọn jáde nínú ìṣòro wọn.