Psalms 107:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
tí ó kó wọn jáde kúrò láàrin àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀n-ọn-nì, láti ìhà ìlà oòrùn ati láti ìhà ìwọ̀ oòrùn, láti ìhà àríwá ati láti ìhà gúsù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si kó wọn jọ lati ilẹ wọnnì wá, lati ila-õrun wá, ati lati ìwọ-õrun, lati ariwa, ati lati okun wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó kó jọ láti ilẹ̀ wọ̀nnì láti ìlà òòrùn àti ìwọ̀ òòrùn, láti àríwá àti òkun wá.