Psalms 107:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí wọn gbé e ga láàrin ìjọ eniyan, kí wọn sì yìn ín ní àwùjọ àwọn àgbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki nwọn ki o gbé e ga pẹlu ni ijọ enia, ki nwọn ki o si yìn i ninu ijọ awọn àgba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí wọn gbé e ga ní àárin àwọn ènìyàn kí wọn kí ó sì yín ín ní ìjọ àwọn àgbà.