Psalms 107:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó sọ ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀ oníyọ̀, nítorí ìwà burúkú àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ eleso di aṣálẹ̀, nitori ìwa-buburu awọn ti o wà ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ eleso di aṣálẹ̀ nítorí ìwà búburú àwọn tí ó wà nínú Rẹ̀;