Psalms 107:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó jẹ́ kí àwọn tí ebi ń pa máa gbé ibẹ̀, wọ́n sì tẹ ìlú dó, láti máa gbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nibẹ li o si mu awọn ti ebi npa joko, ki nwọn ki o le tẹ ilu do, lati ma gbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ó mú ẹni tí ebi ń pa wà, wọ́n sì pìlẹ̀ ibi tí wọn ó máa gbé