Psalms 107:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n dínkù, tí a rẹ̀ wọ́n sílẹ̀, nípa ìnira, ìpọ́njú, ati ìṣòro,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ̀wẹ, nwọn bùku, nwọn si fà sẹhin, nipa inira, ipọnju, ati ikãnu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, ọjọ́ wọn kúrú, ìnira, ìpọ́njú àti ìṣòro wọn sì dínkù