Psalms 107:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kan ń káàkiri ninu aṣálẹ̀, wọn kò sì rí ọ̀nà dé ìlú tí wọ́n lè máa gbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn nrìn ka kiri li aginju ni ibi ti ọ̀na kò si: nwọn kò ri ilu lati ma gbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń rìn káàkiri ni ihà ni ibi tí ọ̀nà kò sí, wọn kòrí ọ̀nà lọ sí ìlú níbi tí wọn ó máa gbé