Psalms 107:40 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ó da ẹ̀gàn lu àwọn ìjòyè, ó sì mú kí wọn máa rìn kiri ní aṣálẹ̀, níbi tí kò sí ọ̀nà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O dà ẹ̀gan lù awọn ọmọ-alade, o si mu wọn rìn kiri ni ijù, nibiti ọ̀na kò si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó da ẹ̀gàn lu ọmọ aládé ó sì mú wọn rìn níbi tí ọ̀nà kò sí