Psalms 107:41 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ó yọ aláìní kúrò ninu ìpọ́njú, ó sì mú kí ìdílé wọn pọ̀ sí i bí agbo ẹran.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sibẹ o gbé talaka leke kuro ninu ipọnju, o si ṣe idile wọnni bi agbo-ẹran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó gbé aláìní sókè kúrò nínú ìnira ó mú ìdílé wọn pọ̀ bi agbo ẹran