Psalms 107:42 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn olódodo rí i, inú wọn dùn, a sì pa àwọn eniyan burúkú lẹ́nu mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ẹni diduro-ṣinṣin yio ri i, nwọn o si yọ̀: gbogbo ẹ̀ṣẹ ni yio si pa ẹnu rẹ̀ mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó dúró sì ríi, inú wọn sì dùn ṣùgbọ́n gbogbo olùṣe búburú yóò pa ẹnu Rẹ̀ mọ́.