Psalms 107:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ebi pa wọ́n, òùngbẹ gbẹ wọ́n, ó sì rẹ̀ wọ́n wá láti inú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ebi pa wọn, ongbẹ si gbẹ wọn, o rẹ̀ ọkàn wọn ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ebi ń pa wọn, òùngbẹ gbẹ wọn, ó sì Rẹ̀ ọkàn wọn nínú wọn.