Psalms 107:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni wọ́n ké pe OLUWA ninu ìpọ́njú wọn, ó sì yọ wọ́n kúrò ninu ìṣẹ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn kigbe pè Oluwa ninu ipọnju wọn, o si yọ wọn kuro ninu iṣẹ́ wọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìgbà náà wọn kígbe sókè sí OLÚWA nínú ìdàámú wọn, ó sì yọ wọ́n kúrò nínú ìrora wọn