Psalms 108:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọ́run, a óo ṣe akin; nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipasẹ Ọlọrun li awa o ṣe akin; nitori on ni yio tẹ̀ awọn ọta wa mọlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípaṣẹ̀ Ọlọ́run ni àwa ó ṣe akin nítorí oun ó tẹ àwọn ọ̀ta wa mọ́lẹ̀.