Psalms 108:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, n óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ láàrin àwọn eniyan, n óo sì máa kọrin ìyìn sí ọ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o ma yìn ọ, Oluwa, ninu awọn enia: emi o mã kọrin si ọ ninu awọn orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ó yìn ọ, Ọlọ́run nínú àwọn orílẹ̀ èdè èmi o kọrin Rẹ nínú àwọn ènìyàn