Psalms 109:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí àwọn ọmọ rẹ̀ di alárìnká, kí wọn máa ṣagbe kiri; kí á lé wọn jáde kúrò ninu ahoro tí wọn ń gbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki awọn ọmọ rẹ̀ ki o di alarinkiri, ti nṣagbe: ki nwọn ki o ma tọrọ onjẹ jina si ibi ahoro wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí àwọn ọmọ Rẹ̀ máa ṣagbe kiri kí wọn máa tọrọ ounjẹ jìnnà sí ibi ahoro wọn