Psalms 109:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí ó má bá aláàánú pàdé, kí ẹnikẹ́ni má sì ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀ tí wọ́n ti di aláìníbaba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ẹnikẹni ki o má wà lati ṣãnu fun u: má si ṣe jẹ ki ẹnikẹni ki o si lati ṣe oju rere fun awọn ọmọ rẹ̀ alainibaba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe jẹ́ kí ẹnikan ṣe àánú fún un tàbí kí wọn káàánú lórí àwọn ọmọ Rẹ̀ aláìní baba