Psalms 109:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí ìran rẹ̀ run, kí orúkọ rẹ̀ parẹ́ lórí àwọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki a ke ati ọmọ-de-ọmọ rẹ̀ kuro, ati ni iran ti mbọ̀ ki orukọ wọn ki o parẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí a gé àrọ́mọdọ́mọ Rẹ̀ kúrò kí orúkọ wọn kí ó parẹ́ ní ìran tí ń bọ̀