Psalms 109:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí OLUWA máa ranti ẹ̀ṣẹ̀ wọn nígbà gbogbo, kí á má sì ranti ìran wọn mọ́ láyé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki nwọn ki o wà niwaju Oluwa nigbagbogbo, ki o le ke iranti wọn kuro lori ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ wọn kí ó wà ní ìrántí níwájú OLÚWA kí o le ge ìrántí wọn kúrò lórí ilẹ̀.