Psalms 109:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé kò ronú láti ṣàánú, ṣugbọn ó ṣe inúnibíni talaka ati aláìní, ati sí oníròbìnújẹ́ títí a fi pa wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti kò ranti lati ṣãnu, ṣugbọn o ṣe inunibini si ọkunrin talaka ati olupọnju nì, ki o le pa onirobinujẹ-ọkàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí kò rántí láti ṣàánú, ṣùgbọ́n ó ṣe inúnibíní sí ọkùnrin tálákà àti olùpọ́njú, kí ó lè pa oníròbìnújẹ́ ọkàn.