Psalms 109:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fẹ́ràn láti máa ṣépè; nítorí náà kí èpè rẹ̀ dà lé e lórí; inú rẹ̀ kò dùn sí ìre, nítorí náà kí ìre jìnnà sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o ti fẹ egun, bẹ̃ni ki o de si i: bi inu rẹ̀ kò ti dùn si ire, bẹ̃ni ki o jina si i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fẹ́ràn láti máa mú ègún wá sí orí Rẹ̀: bi inú Rẹ̀ kò ti dùn si ire, bẹ́ẹ̀ ni ki ó jìnnà sí ì.