Psalms 109:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo di ẹni ẹ̀gàn níwájú àwọn ọ̀tá mi, wọ́n ń wò mí ní àwòmirí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi di ẹ̀gan fun wọn pẹlu: nigbati nwọn wò mi, nwọn mi ori wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo dàbí ẹ̀gàn fún àwọn olùfisùn mi; nígbà tí wọn wò mí, wọn gbọn orí wọn.