Psalms 109:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí wọn máa ṣépè, ṣugbọn kí ìwọ máa súre. Kí ojú ti àwọn alátakò mi, kí inú èmi, iranṣẹ rẹ, sì máa dùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o ma gegun, ṣugbọn iwọ ma sure: nigbati nwọn ba dide, ki oju ki o tì wọn; ṣugbọn iranṣẹ rẹ yio yọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n o máa gégùn-ún, ṣùgbọ́n ìwọ má súré; Nígbà tí wọn bá dìde kí ojú kí ó tì wọ́n, ṣùgbọ́n ìránṣẹ́ Rẹ yóò yọ̀