Psalms 109:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé ó dúró ti aláìní láti gbà á lọ́wọ́ àwọn tí ó dájọ́ ikú fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti yio duro li ọwọ ọtún olupọnju, lati gbà a lọwọ awọn ti o nda ọkàn rẹ̀ lẹbi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ó dúró ni apá ọ̀tún aláìní láti gbà á lọ́wọ́ àwọn tí ń dá ọkàn Rẹ̀ lẹ́bi.