Psalms 11:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ẹ wo àwọn eniyan burúkú bí wọ́n ti kẹ́ ọfà; wọ́n fa ọrun; wọ́n sì fi òkùnkùn bojú láti ta olódodo lọ́fà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sa kiyesi i, awọn enia buburu ti fà ọrun wọn le, nwọn ti fi ọfa sùn li oju ọṣán, ki nwọn ki o le ta a li òkunkun si ọlọkàn diduro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wò ó nítorí náà, ènìyàn búburú fa ọfà Rẹ̀; wọn ti ọfà wọn sí ojú okùn láti tafà níbi òjìjì sí àyà ẹni ìdúró ṣinṣin.