Psalms 11:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀, ìtẹ́ rẹ̀ wà lọ́run; OLUWA ń kíyèsí àwọn ọmọ eniyan, ó sì ń yẹ̀ wọ́n wò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa mbẹ ninu tempili mimọ́ rẹ̀, itẹ́ Oluwa mbẹ li ọrun: oju rẹ̀ nwò, ipenpeju rẹ̀ ndán awọn ọmọ enia wò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ń bẹ nínú tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ̀; OLÚWA ń bẹ lórí ìtẹ́ Rẹ̀ ní ọ̀run. Ó ń wo àwọn ọmọ ènìyàn; ojú Rẹ̀ ń yẹ̀ wọ́n wò.