Psalms 110:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, ọpọlọpọ òkú ni yóo sì sùn ninu wọn; yóo sì run àwọn ìjòyè káàkiri ilẹ̀ ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio ṣe idajọ lãrin awọn keferi, yio fi okú kún ibi wọnni; yio fọ́ ori lori ilẹ pupọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò ṣe ìdájọ́ láàrin kènfèrí, yóò kún ibùgbé wọn pẹ̀lú òkú ara; yóò fọ́n àwọn olórí ká sí orí ilẹ̀ ayé tí ó gbòòrò.