Psalms 111:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ yin OLUWA! N óo dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA tọkàntọkàn, láàrin àwọn olódodo, ati ní àwùjọ àwọn eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ma yìn Oluwa. Emi o ma yìn Oluwa tinutinu mi, ninu ijọ awọn ẹni diduro-ṣinṣin, ati ni ijọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ máa yin OLÚWA. Èmi yóò máa yìn OLÚWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi, ní àwujọ àwọn olóòtọ́, àti ní ijọ ènìyàn.