Psalms 111:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ti fi agbára iṣẹ́ rẹ̀ han àwọn eniyan rẹ̀, nípa fífún wọn ní ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti fi iṣẹ agbara rẹ̀ hàn awọn enia rẹ̀, ki o le fun wọn ni ilẹ-ini awọn keferi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ti fi hàn àwọn ènìyàn Rẹ̀ agbára isẹ́ Rẹ̀ láti fún wọn ní ilẹ̀lérí ni ìní