Psalms 112:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó lawọ́, á máa ṣoore fún àwọn talaka, òdodo rẹ̀ wà títí lae, yóo di alágbára, a óo sì dá a lọ́lá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti fún ka, o ti fi fun awọn olupọnju; ododo rẹ̀ duro lailai; ọlá li a o fi gbé iwo rẹ̀ ga.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ti pin ká, ó ti fi fún àwọn olùpọ́njú; Nítorí òdodo Rẹ̀ dúró láé; ìwọ Rẹ̀ ní a ó gbé sókè pẹ̀lú ọlá.