Psalms 113:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ju gbogbo orílẹ̀-èdè lọ, ògo rẹ̀ sì ga ju ọ̀run lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa ga lori gbogbo orilẹ-ède, ogo rẹ̀ si wà lori ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ga lórí gbogbo ayé, àti ògo Rẹ̀ lórí àwọn ọ̀run.