Psalms 113:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti mú wọn jókòó láàrin àwọn ìjòyè, àní, àwọn ìjòyè àwọn eniyan rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o le mu u joko pẹlu awọn ọmọ-alade, ani pẹlu awọn ọmọ-alade awọn enia rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ó le mú-un jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ aládé àní pẹ̀lú àwọn ọmọ aládé àwọn ènìyàn Rẹ̀.