Psalms 114:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, tí àwọn ọmọ Jakọbu jáde kúrò láàrin àwọn tí ń sọ èdè àjèjì,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBATI Israeli jade kuro ni Egipti, ti ara-ile Jakobu kuro ninu àjeji ède enia;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Ísírẹ́lì jáde ní Éjíbítì, ilé Jákọ́bù láti inú ènìyàn àjòjì èdè