Psalms 115:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ló ni ọ̀run, ṣugbọn ó fi ayé fún àwọn eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrun ani ọrun ni ti Oluwa; ṣugbọn aiye li o fi fun awọn ọmọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀run àní ọ̀run ni ti, OLÚWA: ṣùgbọ́n ayé lo fi fún ọmọ ènìyàn.