Psalms 115:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn òkú kò lè yin OLUWA, àní àwọn tí wọ́n ti dákẹ́ ninu ibojì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Okú kò yìn Oluwa, ati gbogbo awọn ti o sọkalẹ lọ sinu idakẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òkú kò le yìn OLÚWA, tàbí ẹni tí o ti lọ sí ìṣàlẹ̀ ìdákẹ́jẹ́.