Psalms 115:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n lọ́wọ́, ṣugbọn wọn kò lè lò ó, wọ́n lẹ́sẹ̀, ṣugbọn wọn kò lè rìn, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò lè gbin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn li ọwọ, ṣugbọn nwọn kò lò o: nwọn li ẹsẹ, ṣugbọn nwọn kò rìn: bẹ̃ni nwọn kò sọ̀rọ lati ọfun wọn jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ní ọwọ́, ṣùgbọ́n wọn kò lò ó, wọ́n ní ẹṣẹ̀, ṣùgbọ́n wọn kò rìn; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kò sọ̀rọ̀ nínú òfin wọn.