Psalms 115:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí ó ń yá àwọn ère náà dàbí wọn, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti nṣe wọn dabi wọn; bẹ̃li olukuluku ẹniti o gbẹkẹle wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ń ṣe wọ́n dàbí wọn; gẹ́gẹ́ bẹ ni olúkúlùkù ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀ Rẹ̀ lé wọn.