Psalms 116:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Igbagbọ mi kò yẹ̀, nígbà tí mo tilẹ̀ wí pé, “Ìpọ́njú dé bá mi gidigidi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi gbagbọ́, nitorina li emi ṣe sọ: mo ri ipọnju gidigidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, “èmi rí ìpọ́njú púpọ̀”.