Psalms 116:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé ó tẹ́tí sí mi, nítorí náà, n óo máa ké pè é níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti o dẹ eti rẹ̀ si mi, nitorina li emi o ma kepè e niwọn ọjọ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ó yí etí Rẹ̀ padà sí mi, èmi yóò máa, pè é ní wọ̀n ìgbà tí mo wà láàyé.