Psalms 116:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA a máa pa àwọn onírẹ̀lẹ̀ mọ́; nígbà tí a rẹ̀ mí sílẹ̀, ó gbà mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa pa awọn alaimọ̀kan mọ́: a rẹ̀ mi silẹ tan, o si ràn mi lọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA pa àwọn ọlọ́kàn fífúyẹ́ mọ́ nígbà tí mo wà nínú àìní ńlá, ó gbà mí.