Psalms 118:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo orílẹ̀-èdè dòòyì ká mi, ṣugbọn ní orúkọ OLUWA, mo pa wọ́n run!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn orilẹ-ède yi mi ka kiri, ṣugbọn li orukọ Oluwa emi o pa wọn run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè yí mi káàkiri, ṣùgbọ́n ní orúkọ OLÚWA èmi gé wọn kúrò