Psalms 118:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n yí mi ká, àní, wọ́n dòòyì ká mi, ṣugbọn ni orúkọ OLUWA, mo pa wọ́n run!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn yi mi ka kiri; nitõtọ, nwọn yi mi ka kiri, ṣugbọn li orukọ Oluwa emi o pa wọn run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yí mi ká kiri ní gbogbo ẹ̀gbẹ́, ṣùgbọ́n ní orúkọ OLÚWA èmi gé wọn dànù